Ísíkẹ́lì 20:33 BMY

33 Bí mo ti wà láàyè ní Olúwa Ọlọ́run wí, ń ó jọba lórí yín pẹ̀lú ọwọ́ agbára tí ń ó nà jáde pẹ̀lú ìtújáde ìbínú gbígbóná mi.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:33 ni o tọ