Ísíkẹ́lì 20:34 BMY

34 Èmi yóò mú yín jáde láàrin àwọn ènìyàn, èmi yóò sì ṣà yín jọ láàrin àwọn orílẹ̀ èdè tí a fọ́n yín sí pẹ̀lú ọwọ́ agbára tí èmi yóò nà jáde àti pẹ̀lú ìtújáde ìbínú gbígbóná ni.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:34 ni o tọ