Ísíkẹ́lì 20:4 BMY

4 “Ìwọ fẹ́ dájọ́ wọn bí? Ìwọ fẹ dájọ́ wọn bí ọmọ ènìyàn? Nítorí náà fi gbogbo ìwà ìríra baba wọn kò wọ́n lójú,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:4 ni o tọ