Ísíkẹ́lì 20:3 BMY

3 “Ọmọ ènìyàn, sọ fún àwọn àgbà Ísírẹ́lì, kì ó sì wí fún wọn pé, ‘Báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí: Ṣe ki ẹ lè wádìí lọ́dọ̀ mi ni ẹ ṣe wá? Bí mo ti wà láàyè ní Olúwa Ọlọ́run wí. N ò ní í gbà kí ẹ wádìí lọ́dọ̀ mi.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:3 ni o tọ