Ísíkẹ́lì 22:2 BMY

2 “Ọmọ ènìyàn ǹjẹ́ ìwọ yóò ha ṣe ìdájọ́ rẹ̀? Ǹjẹ́ ìwọ ha ṣe ìdájọ́ ìlú atàjẹ̀sílẹ̀? Tó bá rí bẹ́ẹ̀ dojúkọ wọn pẹ̀lú gbogbo ìwà ìríra wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 22

Wo Ísíkẹ́lì 22:2 ni o tọ