Ísíkẹ́lì 22:3 BMY

3 Kí ó sì wí pé: ‘Èyí yìí ní ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Ìwọ ìlú ńlá tí ó mú ìparun wá sórí ara rẹ nípa títàjẹ̀sílẹ̀ ní àárin rẹ, tí ó sì ba ara rẹ̀ jẹ́ nípa ṣíṣe àwọn ère,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 22

Wo Ísíkẹ́lì 22:3 ni o tọ