Ísíkẹ́lì 23:3 BMY

3 Wọn ń ṣe panṣágà ní Éjíbítì, wọn ń ṣe panṣaga láti ìgbà èwe wọn. Ní ilẹ̀ yẹn ni wọn ti fi ọwọ́ pa ọyàn wọn, níbẹ̀ ni wọn sì fọwọ́ pa igbá àyà èwe wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:3 ni o tọ