4 Èyí ẹ̀gbọ́n ń jẹ́ Óhólà, àbúrò rẹ̀ sì ń jẹ́ Óhólíbà. Tèmí ni wọn, wọ́n sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin. Óhólà ni Samaríà, Óhólíbà sì ni Jérúsálẹ́mù.
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23
Wo Ísíkẹ́lì 23:4 ni o tọ