Ísíkẹ́lì 23:46 BMY

46 “Èyí ni ohun tí Olúwa Olódùmarè wí: Mú àgbájọ àwọn ènìyàn kénìyàn wá sọ́dọ̀ wọn ki ó sì fi wọn lé ọwọ́ ìpayà àti ìkógun.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:46 ni o tọ