Ísíkẹ́lì 23:47 BMY

47 Àwọn ènìyànkénìyàn náà yóò sọ wọ́n ni òkúta, yóò sì gé wọn lulẹ̀ pẹ̀lú idà wọn; wọn ó sì pa àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin wọn, wọ́n ó sì jó àwọn ilé wọn kanlẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 23

Wo Ísíkẹ́lì 23:47 ni o tọ