Ísíkẹ́lì 25:13 BMY

13 nítorí náà báyìí ní Olúwa Olódùmarè wí pé: Èmi yóò na ọwọ́ mi sórí Édómù èmi yóò sì pa àwọn ènìyàn àti àwọn ẹranko rẹ̀. Èmi yóò fi sófo láti Temanì dé Dédánì yóò ti ipa idà ṣsubú.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 25

Wo Ísíkẹ́lì 25:13 ni o tọ