Ísíkẹ́lì 25:14 BMY

14 Èmi yóò gbẹ̀san lára Édómù láti ọwọ́ àwọn ènìyàn mi Ísírẹ́lì, wọn sì se ṣsi Édómù gẹ́gẹ́ bí ìbínú àti ìrunú mi: wọn yóò mọ̀ ìgbẹ̀san mi ní Olúwa Ọlọ́run wí.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 25

Wo Ísíkẹ́lì 25:14 ni o tọ