Ísíkẹ́lì 25:15 BMY

15 “Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí pé: ‘Nítorí tí àwọn ará Fílísítíà hùwà ẹ̀san tí wọ́n sì gbẹ̀san pẹ̀lú odì ní ọkàn wọn, àti pẹ̀lú ìjà gbangba àtijọ́ ní wíwá ọ̀nà láti pa Júdà run,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 25

Wo Ísíkẹ́lì 25:15 ni o tọ