Ísíkẹ́lì 25:16 BMY

16 nítorí náà báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí pé: Èmi ti ṣetán láti na ọwọ́ mi jáde sí àwọn ará Fílísítíà Èmi yóò sì ké àwọn ará Kérétì kúrò, Èmi yóò sì pa àwọn tí ó kù ní etí kún run.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 25

Wo Ísíkẹ́lì 25:16 ni o tọ