Ísíkẹ́lì 25:6 BMY

6 Nítorí báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Nítorí pé ìwọ pàtẹ́wọ́, ìwọ sì jan ẹsẹ̀ mọ́lẹ̀, tí ìwọ ń yọ̀ pẹ̀lú gbogbo àrankàn rẹ sí ilẹ̀ Ísírẹ́lì

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 25

Wo Ísíkẹ́lì 25:6 ni o tọ