2 “Ọmọ ènìyàn, nítorí pé Tírè sọ nípa Jérúsálẹ́mù pé, ‘Áà! A fọ́ èyí tí í ṣe bodè àwọn orílẹ̀-èdè, a yí i padà sí mi, èmi yóò di kíkún, òun yóò sì di ahoro,’
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 26
Wo Ísíkẹ́lì 26:2 ni o tọ