Ísíkẹ́lì 27:22 BMY

22 “ ‘Àwọn oníṣòwò ti Ṣébà àti Rámà, àwọn ni oníṣòwò rẹ; wọ́n ta onírúurú tùràrí olóòórùn dídùn dáradára ní ọjà rẹ, àti àwọn òkúta iyebíye àti wúrà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 27

Wo Ísíkẹ́lì 27:22 ni o tọ