Ísíkẹ́lì 29:15 BMY

15 Ibẹ̀ yóò jẹ́ ìjọba tí ó rẹ̀lẹ̀ jùlọ nínú àwọn ìjọba, kì yóò sì gbé ara rẹ̀ ga mọ́ sórí àwọn orílẹ̀-èdè: nítorí èmi ni ó dín wọn kù, ti wọn kì yóò fi ṣe olórí àwọn orílẹ̀-èdè yòókù mọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:15 ni o tọ