Ísíkẹ́lì 29:16 BMY

16 Éjíbítì kí yóò sì jẹ orísun ìgbẹ́kẹ̀lé fún ilé Ísírẹ́lì mọ́ ṣùgbọ́n, yóò jẹ́ ìrántí fún àìṣedédé wọn, nígbà tí yóò bá wò wọ́n fún ìrànlọ́wọ́. Nígbà náà, wọn yóò mọ̀ pé èmi ni Olúwa Ọlọ́run.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:16 ni o tọ