Ísíkẹ́lì 29:17 BMY

17 Ó sì ṣe ní ọjọ́ kìn-ín-ní, oṣù kìn-ín-ní, ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n, ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá wí pé:

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:17 ni o tọ