Ísíkẹ́lì 29:18 BMY

18 “Ọmọ ènìyàn, Nebukadinésárì ọba Bábílónì mú kí ogun rẹ sin ìrú ńlá fún Tírè. Gbogbo ori pá, àti gbogbo èjìká bó, ṣíbẹ̀, òun àti àwọn ogun rẹ̀, kò rí owo ọ̀yà gbà láti Tírè fún wa, fún ìrú ti a ti sìn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:18 ni o tọ