Ísíkẹ́lì 29:19 BMY

19 Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Kíyèsí i, Èmi yóò fi Éjíbítì fún Nebukadinésárì ọba Bábílónì, òun yóò sì kó ọrọ̀ rẹ̀ lọ. Òun yóò bo ilé, yóò sì ṣe ìkógun ilẹ̀ náà gẹ́gẹ́ bí owó iṣẹ́ tí a san fún ológun rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:19 ni o tọ