Ísíkẹ́lì 29:20 BMY

20 Èmi ti fi Éjíbítì fún un gẹ́gẹ́ bí èrè wàhálà rẹ̀ nítorí òun àti àwọn ológun rẹ ṣe é fún mi, ni Olúwa Ọlọ́run wí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:20 ni o tọ