21 “Ní ọjọ́ náà, èmi yóò mú kí ilé Ísírẹ́lì ní agbára, èmi yóò sì fún ọ ní ẹnu ọ̀rọ̀ ní àárin wọn. Nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé èmi ni Olúwa.”
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29
Wo Ísíkẹ́lì 29:21 ni o tọ