Ísíkẹ́lì 30:2 BMY

2 “Ọmọ ènìyàn, ṣọtẹ́lẹ̀ kí o sì wí pé: ‘Báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Pohùnréré ẹkún kí o sì wí pé,“Ó ṣe fún ọjọ́ náà!”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 30

Wo Ísíkẹ́lì 30:2 ni o tọ