Ísíkẹ́lì 30:22 BMY

22 Nítorí náà, báyìí ní Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Èmi lòdì sí Fáráò Ọba Éjíbítì. Èmi yóò sẹ́ apá rẹ̀ méjèèjì, èyí tí ó dára àti èyí tí a ti ṣẹ́ pẹ̀lú, yóò sì mú kí idà bọ́ sọnù ní ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 30

Wo Ísíkẹ́lì 30:22 ni o tọ