Ísíkẹ́lì 30:23 BMY

23 Èmi yóò sì fọ́n àwọn ènìyàn Éjíbítì ká sí àárin àwọn orílẹ̀ èdè, èmi yóò sì tú wọn ká gbogbo ilẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 30

Wo Ísíkẹ́lì 30:23 ni o tọ