Ísíkẹ́lì 32:4 BMY

4 Èmi yóò jù ọ́ sí orí ilẹ̀èmi yóò sì fà ọ́ sókè sí orí pápá gbangba.Èmi yóò jẹ́ kí gbogbo ẹyẹ ojú ọ̀run ṣeàtìpó ní orí rẹ.Gbogbo àwọn ẹranko ayé yóò fiìwọra gbé ara wọn mù lórí rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 32

Wo Ísíkẹ́lì 32:4 ni o tọ