Ísíkẹ́lì 33:21 BMY

21 Ní ọjọ́ karùn ún oṣù kẹ́wàá, ọdún kejìlá ìkólọ wa, ọkùnrin kan tí ó sá kúrò ni Jerúsálẹ́mù wá sọ́dọ̀ mi, ó sì wí pé, “Ìlú ńlá náà ti ṣubú!”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 33

Wo Ísíkẹ́lì 33:21 ni o tọ