Ísíkẹ́lì 33:22 BMY

22 Ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ tí ó ku ọ̀la tí ẹni tí ó sálọ náà yóò dé, ọwọ́ Olúwa sì níbẹ lára mi, o sì ya ẹnu mi ki ọkùnrin náà tó wá sọ́dọ̀ mi sílẹ̀ èmi kò sì lè dákẹ́ mọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 33

Wo Ísíkẹ́lì 33:22 ni o tọ