Ísíkẹ́lì 34:5 BMY

5 Nítorí náà wọn fọ́n káàkiri nítorí àìsí olùsọ́ àgùntàn, nígbà tí wọ́n fọ́n ká tán wọn di ìjẹ fún gbogbo ẹranko búburú.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:5 ni o tọ