Ísíkẹ́lì 36:12 BMY

12 Èmi yóò mú kí àwọn ènìyàn, àní àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì, rìn lórí rẹ̀. Wọn yóò gbà ọ́, ìwọ yóò sì di ogún ìní wọn; ìwọ kì yóò sì gba àwọn ọmọ wọn lọ́wọ́ wọn mọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:12 ni o tọ