Ísíkẹ́lì 36:13 BMY

13 “ ‘Èyí yìí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Nítorí pé àwọn ènìyàn sọ fún ọ pé, “Ìwọ pa àwọn ènìyàn run, ìwọ sì gba àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè lọ́wọ́ wọn,”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:13 ni o tọ