Ísíkẹ́lì 38:14 BMY

14 “Nítorí náà, ọmọ ènìyàn, ṣọtẹ́lẹ̀ kí ó sì ṣọ fún Gógì: ‘Èyí yìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Ní ọjọ́ náà, nígbà tí àwọn ènìyàn mi Ísírẹ́lì ń gbé ní àìléwu, ìwọ kì yóò ha ṣe àkíyèsí rẹ̀?

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 38

Wo Ísíkẹ́lì 38:14 ni o tọ