Ísíkẹ́lì 38:15 BMY

15 Ìwọ yóò wá láti ààyè rẹ ní jìnnàjìnnà àríwá, ìwọ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀ èdè pẹ̀lú rẹ, gbogbo wọn yóò sì gun ẹsìn ìjọ ńlá, jagunjagun alágbára.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 38

Wo Ísíkẹ́lì 38:15 ni o tọ