Ísíkẹ́lì 38:17 BMY

17 “ ‘Èyí yìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Ìwọ ha kọ́ ni mo ṣọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ ní ìgbà ìṣáájú láti ẹnu àwọn ìránṣẹ́ mi ti Ísírẹ́lì? Ní ìgbà náà wọ́n ṣọtẹ́lẹ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún pé èmi yóò mú ọ lòdì sí wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 38

Wo Ísíkẹ́lì 38:17 ni o tọ