Ísíkẹ́lì 38:18 BMY

18 Èyí ni ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ náà: Nígbà tí Gógì bá kọlu ilẹ̀ Ísírẹ́lì, gbígbóná ibínú mi yóò ru sókè, ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 38

Wo Ísíkẹ́lì 38:18 ni o tọ