Ísíkẹ́lì 38:23 BMY

23 Nítorí náà, Èmi yóò fi títóbi mi àti ìjẹ́-mímọ́ mi hàn, Èmi yóò sì fi ara mi hàn ní ojú ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀ èdè. Nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 38

Wo Ísíkẹ́lì 38:23 ni o tọ