Ísíkẹ́lì 39:6 BMY

6 Èmi yóò fi iná sí mágógì àti sí àwọn tí ń gbé ní agbègbè ilẹ̀ ibẹ̀ ní àìléwu, wọn yóò sì mọ̀ pé èmi ni Olúwa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 39

Wo Ísíkẹ́lì 39:6 ni o tọ