Ísíkẹ́lì 4:9 BMY

9 “Mú ọkà bàbà àti àlìkámà, erèé àti lẹ́ńtìlì, jéró àti ẹwẹ; fi àwọn nǹkan wọ̀nyí ṣe àkàrà tí ìwọ yóò máa jẹ nígbà tí ìwọ bá dùbúlẹ̀ fún irinwó ọjọ́ ó dín mẹ́wàá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 4

Wo Ísíkẹ́lì 4:9 ni o tọ