Ísíkẹ́lì 40:26 BMY

26 Àtẹ̀gùn méje ní ó dé ibẹ̀, pẹ̀lú àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà ní òdì kejì wọn; Ó ní igi ọ̀pẹ tí a fi ṣe ọ̀ṣọ́ rẹ̀ ni ojú ìgbéró ògiri ní ẹ̀gbẹ́ kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:26 ni o tọ