Ísíkẹ́lì 40:3 BMY

3 Ó mú mi lọ síbẹ̀, mo sì rí ọkùnrin kan tí ìrírí rẹ̀ dàbí ìrí bàba; ó dúró ni ẹnu ọ̀nà pẹ̀lú okùn aṣọ ọ̀gbọ̀ funfun àti ọ̀pá ìwọnlẹ̀ ní ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:3 ni o tọ