Ísíkẹ́lì 41:1 BMY

1 Lẹ́yìn náà ọkùnrin náà mú mi lọ sí ìta ibi mímọ́, ó sì wọn àwọn àtẹ́rígbà náà; ìbú atẹrígbà náà sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́fà ní ègbẹ́ kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 41

Wo Ísíkẹ́lì 41:1 ni o tọ