Ísíkẹ́lì 43:27 BMY

27 Ní ìparí ọjọ́ wọ̀nyí, láti ọjọ́ mẹ́jọ síwájú, àwọn àlùfáà ni yóò gbé àwọn ẹbọ sísun rẹ àti ẹbọ ìdàpọ̀ rẹ̀ kalẹ̀ lórí pẹpẹ. Lẹ́yìn náà, èmi yóò tẹ́wọ́gba yín ní Olúwa Ọba wí.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 43

Wo Ísíkẹ́lì 43:27 ni o tọ