Ísíkẹ́lì 44:1 BMY

1 Lẹ́yìn náà ni ọkùnrin náà mú mi padà lọ sí ibi mímọ́, èyí tí ó kọjú sí ìhà ìlà oòrùn, ó sì wà ní títì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:1 ni o tọ