Ísíkẹ́lì 44:10 BMY

10 “ ‘Àwọn Léfì tí wọn rìn jìnnà kúrò lọ́dọ̀ mi nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sìnà, ti wọ́n sì ṣáko kúrò lọ́dọ̀ mi láti tọ àwọn ère wọn lẹ́yìn gbọdọ̀ jèrè ẹ̀sẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:10 ni o tọ