Ísíkẹ́lì 44:9 BMY

9 Èyí yìí ní Olúwa Ọba wí: Àjòjì aláìkọlà àyà àti ara kò gbọdọ̀ wọ ibi mímọ́ mi, àti pẹ̀lú àwọn àjòjì tí ń gbé ní àárin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:9 ni o tọ