Ísíkẹ́lì 44:20 BMY

20 “ ‘Wọn kò gbọdọ̀ fá irun, wọn kò sì gbọdọ̀ jẹ́ kí irun wọn gùn, ṣùgbọ́n wọn gbọdọ̀ jẹ́ kí irun orí wọn wà ní gígẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:20 ni o tọ