Ísíkẹ́lì 44:30 BMY

30 Èyí tí ó dára jùlọ nínú gbogbo àkọ́so èso àti ti ẹ̀bùn pàtàkì yóò jẹ́ ti àwọn àlùfáà. Ẹ ní láti fún wọn ní ìpín àkọ́kọ́ nínú èso ilẹ̀ yìí kí ìbùkún lè wà lórí gbogbo ilé yìí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:30 ni o tọ