Ísíkẹ́lì 45:19 BMY

19 Àlùfáà ni yóò mú díẹ̀ nínú ẹ̀jẹ̀ ọrẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, kí o sì fi si ẹnu ilẹkùn ilé Ọlọ́run, àti sí ara àwọn ilẹ̀kùn tí ó wà ní àgbàlá ti inú.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:19 ni o tọ